Welcome to your one stop online student help centre, a place where everybody is admin.
HOME
JAMB EXAM ↓
POST UTME EXAM ↓
NEWS
ALL STUDENT FORUM
JAMB FORUM
ADMISSION FORUM
QUESTION & ANSWER
DOWNLOAD
STUDENT CONNECT
ABOUT US
Log in / Sign up
DONATE
Javascript is turn off, turn On javascript in your browser and reload the page.
Yoruba QUESTION REVIEW - (JAMB)
1
.
U je faweli
A
ayanupe
B
ahanupe
C
ahanudiepe
D
ayanudiepe
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
2
.
Ipin si silebu Osundahunsi ni
A
o-sun-dahun-si
B
osun-da-hun-si
C
osun-da-hunsi
D
o-sun-da-hun-si
=>
Add comment (
1
)
Detail
Share
Edit
Delete
3
.
orìsà ti a máa n fi eyín erin bô ni
A
Ela
B
ogun
C
sango
D
orunmila
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
4
.
Iru ènìyàn ti ìyàwo ile le gbà ní àlejo ni
A
iyèkan rê lökunrin
B
iyèkan rê löbirin
C
ôbàkan rê lökunrin
D
ôbàkan rê löbinrin
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
5
.
Nínú "Mo ra ile títobi", títobi jë êyán
A
asonka
B
asapejuwe
C
onibatan
D
asafihan
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
6
.
A yá àlubösà lo láti inú èdè?
A
hausa
B
ebira
C
larubawa
D
giriki
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
7
.
so ìtumo "The committee will look into the crisis"
A
Ìgbìmõ yoo dá sí aáwõ náà
B
Ìgbìmõ á lè dá sí aáwõ náà
C
Ìgbìmo lè dá sí aáwo náà
D
Ìgbìmõ á ti dá sí aáwõ náà
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
8
.
Ewo ni àfetíyá nínú ìwõnyí?
A
koomu
B
bibeli
C
peteru
D
tabili
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
9
.
Dá iná di Dáná nípasê
A
iyopo
B
aranmo
C
ankoo faweli
D
ipaje faweli
=>
Add comment (
0
)
Detail
Share
Edit
Delete
10
.
Õrõ wo ni ko ní apààlà sílebu nínú "Olú á ra bàtà?
A
Olu
B
a
C
ra
D
bata
=>
Add comment (
1
)
Detail
Share
Edit
Delete
All Question Menu
Free Online Practice Exam
Back To Top
Javascript is turn off.